Letra de Mo nifẹ rẹ John

Mo nifẹ rẹ John, mo nifẹ rẹ
Nitori ifẹ l'okan mi
Igba t'Oluwa ba ti gba mi lowo
A o ri 'yanu re laye

Ifẹ to dara pupọ, ifẹ to dun ju lo
Ko si eni to le pese tire at'ife wa
Ni igbesi aye wa, ni ala wa,
Ni ominira wa, ni aye wa

Mo nifẹ rẹ John, mo nifẹ rẹ
Nitori ife l'okan mi
Igba t'Oluwa ba ti gba mi lowo
A o ri 'yanu re laye


Mo nifẹ rẹ John, mo nifẹ rẹ (x2)